Iṣe Apo 2:3-4
Iṣe Apo 2:3-4 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ẹla ahọn bi ti iná si yọ si wọn, o pin ara rẹ̀ o si bà le olukuluku wọn. Gbogbo nwọn si kún fun Ẹmí Mimọ́, nwọn si bẹ̀rẹ si ifi ède miran sọrọ, gẹgẹ bi Ẹmí ti fun wọn li ohùn.
Pín
Kà Iṣe Apo 2