Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 2:27YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitoriti iwọ ki yio fi ọkàn mi silẹ ni ipò-okú, bẹ̃ni iwọ ki yio jẹ ki Ẹni-Mimọ́ rẹ ki o ri idibajẹ.
Iṣe Apo 2:27BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí tí ìwọ kí yóò fi ọkàn mi sílẹ̀ ni isà òkú, bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kí yóò jẹ́ kí Ẹni Mímọ́ rẹ rí ìdíbàjẹ́.
Iṣe Apo 2:27YCE(Yoruba Bible)
nítorí o kò ní fi ọkàn mi sílẹ̀ ní ibùgbé àwọn òkú; bẹ́ẹ̀ ni o kò ní jẹ́ kí ẹni mímọ́ rẹ rí ìdíbàjẹ́.
Pín
Iṣe Apo 2YCE