Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 2:16YBCV(Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn eyi li ọ̀rọ ti a ti sọ lati ẹnu woli Joeli wá pe
Iṣe Apo 2:16BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bẹ́ẹ̀ kọ́, èyí ni ọ̀rọ̀ ti a ti sọ láti ẹnu wòlíì Joẹli wá pé
Iṣe Apo 2:16YCE(Yoruba Bible)
Ṣugbọn ohun tí Joẹli, wolii Ọlọrun ti sọ wá ṣẹ lónìí, tí ó wí pé
Pín
Iṣe Apo 2YCE