Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 2:12YBCV(Bibeli Mimọ)
Hà si ṣe gbogbo wọn, o si rú wọn lojú, nwọn wi fun ara wọn pe, Kili a le mọ̀ eyi si?
Iṣe Apo 2:12BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹnu sì ya gbogbo wọn, wọ́n sì wárìrì. Wọn wí fún ara wọn pé, “Kí ni èyí túmọ̀ sí?”
Iṣe Apo 2:12YCE(Yoruba Bible)
Ìdààmú bá gbogbo àwọn eniyan, ó pá wọn láyà. Wọ́n ń bi ara wọn pé, “Kí ni ìtumọ̀ èyí?”
Pín
Iṣe Apo 2YCE