Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 2:11YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn ara Krete ati Arabia, awa gbọ́ nwọn nsọ̀rọ iṣẹ iyanu nla Ọlọrun li ède wa.
Iṣe Apo 2:11BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
(àti àwọn Júù àti àwọn tí a ti ipa ẹ̀sìn sọ di Júù); àwọn ará Krete àti Arabia; àwa gbọ́ tí wọ́n sọ̀rọ̀ iṣẹ́ ìyanu ńlá Ọlọ́run ni èdè wa.”
Iṣe Apo 2:11YCE(Yoruba Bible)
àwọn Juu ati àwọn aláwọ̀ṣe ẹ̀sìn Juu; àwọn ará Kirete ati àwọn ará Arabia, gbogbo wa ni a gbọ́ tí wọ́n ń sọ àwọn iṣẹ́ ńlá Ọlọrun ní oríṣìíríṣìí èdè wa.”
Pín
Iṣe Apo 2YCE