Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 18:17YBCV(Bibeli Mimọ)
Gbogbo awọn Hellene si mu Sostene, olori sinagogu, nwọn si lù u niwaju itẹ idajọ. Gallioni kò si ṣú si nkan wọnyi.
Iṣe Apo 18:17BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Gbogbo àwọn Giriki sì mú Sostene, olórí Sinagọgu, wọ́n sì lù ú níwájú ìtẹ́ ìdájọ́. Gallioni kò sì bìkítà fún nǹkan wọ̀nyí.
Iṣe Apo 18:17YCE(Yoruba Bible)
Ni gbogbo wọ́n bá mú Sositene, olórí ilé ìpàdé àwọn Juu, wọ́n ń lù ú níwájú kóòtù. Ṣugbọn Galio kò pé òun rí wọn.