Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 17:7YBCV(Bibeli Mimọ)
Awọn ẹniti Jasoni gbà si ọdọ: gbogbo awọn wọnyi li o si nhuwa lodi si aṣẹ Kesari, wipe, ọba miran kan wà, Jesu.
Iṣe Apo 17:7BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn ẹni tí Jasoni gbà sí ọ̀dọ̀: gbogbo àwọn wọ̀nyí ni o sí ń hùwà lòdì sí àṣẹ Kesari, wí pé, ọba mìíràn kan wà tí í ṣe Jesu.”
Iṣe Apo 17:7YCE(Yoruba Bible)
Jasoni sì ti gbà wọ́n sílé. Gbogbo wọn ń ṣe ohun tí ó lòdì sí àṣẹ Kesari. Wọ́n ní: ọba mìíràn wà, ìyẹn ni Jesu!”