Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 15:6YBCV(Bibeli Mimọ)

Ati awọn aposteli ati awọn àgbagbà pejọ lati gbìmọ ọ̀ran yi.

Iṣe Apo 15:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Àwọn aposteli àti àwọn alàgbà péjọ láti rí si ọ̀ràn yìí.

Iṣe Apo 15:6YCE(Yoruba Bible)

Gbogbo àwọn aposteli ati àwọn àgbààgbà bá péjọ láti rí sí ọ̀rọ̀ yìí.