Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 15:30YBCV(Bibeli Mimọ)

Njẹ nigbati nwọn si jọwọ wọn lọwọ lọ, nwọn sọkalẹ wá si Antioku: nigbati nwọn si pè apejọ, nwọn fi iwe na fun wọn.

Iṣe Apo 15:30BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ǹjẹ́ nígbà tí wọ́n sì fi wọ́n sílẹ̀ láti lọ, wọ́n sọ̀kalẹ̀ wá si Antioku. Nígbà tí wọn sì pé àwọn ìjọ papọ̀, wọn fi ìwé náà fún wọn.

Iṣe Apo 15:30YCE(Yoruba Bible)

Nígbà tí àwọn tí a rán kúrò, wọ́n dé Antioku, wọ́n pe gbogbo ìjọ, wọ́n fún wọn ní ìwé náà.