Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 14:8YBCV(Bibeli Mimọ)
Ọkunrin kan si joko ni Listra, ẹniti ẹsẹ rẹ̀ kò mokun, arọ lati inu iya rẹ̀ wá, ti kò rìn ri.
Iṣe Apo 14:8BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ọkùnrin kan sí jókòó ni Lysra, ẹni tí ẹsẹ̀ rẹ̀ kò mókun, arọ láti inú ìyá rẹ̀ wá, tí kò rìn rí.
Iṣe Apo 14:8YCE(Yoruba Bible)
Ọkunrin kan wà ní ìjókòó ní Listira tí ó yarọ. Láti ìgbà tí wọ́n ti bí i ni ó ti yarọ, kò fi ẹsẹ̀ rẹ̀ rìn rí.