Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 14:5YBCV(Bibeli Mimọ)
Bi awọn Keferi, ati awọn Ju pẹlu awọn olori wọn ti fẹ kọlù wọn lati ṣe àbuku si wọn, ati lati sọ wọn li okuta
Iṣe Apo 14:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí àwọn aláìkọlà, àti àwọn Júù pẹ̀lú àwọn olórí wọn ti fẹ́ kọlù wọ́n láti fi àbùkù kàn wọ́n, àti láti sọ wọ́n ní òkúta
Iṣe Apo 14:5YCE(Yoruba Bible)
Àwọn Juu ati àwọn tí kì í ṣe Juu pẹlu àwọn ìjòyè wọn dábàá láti ṣe wọ́n lọ́ṣẹ́, wọ́n fẹ́ sọ wọ́n ní òkúta pa.