Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 14:28YBCV(Bibeli Mimọ)

Ki iṣe igba diẹ ni nwọn ba awọn ọmọ-ẹhin gbé.

Iṣe Apo 14:28BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Níbẹ̀ ni wọ́n ń gbé pẹ̀lú àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ni ọjọ́ púpọ̀.

Iṣe Apo 14:28YCE(Yoruba Bible)

Wọ́n dúró níbẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn onigbagbọ fún ìgbà pípẹ́.