Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 14:26YBCV(Bibeli Mimọ)

Ati lati ibẹ̀ lọ nwọn ba ti ọkọ̀ lọ si Antioku, lati ibiti a gbé ti fi wọn le õre-ọfẹ Ọlọrun lọwọ, fun iṣẹ ti nwọn ṣe pari.

Iṣe Apo 14:26BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Àti láti ibẹ̀ lọ wọ́n ṣíkọ̀ lọ sí Antioku ní ibi tí a gbé ti fi wọ́n lé oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run lọ́wọ́, fún iṣẹ́ tí wọ́n ṣe parí.

Iṣe Apo 14:26YCE(Yoruba Bible)

Wọ́n wọ ọkọ̀ ojú omi láti ibẹ̀ lọ sí Antioku ní Siria níbi tí wọ́n ti kọ́ fi wọ́n sábẹ́ ojurere Ọlọrun fún iṣẹ́ tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ parí.