Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 13:44YBCV(Bibeli Mimọ)
Li ọjọ isimi keji, gbogbo ilu si fẹrẹ pejọ tan lati gbọ́ ọ̀rọ Ọlọrun.
Iṣe Apo 13:44BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ ìsinmi kejì, gbogbo ìlú sí fẹ́rẹ̀ péjọ tan láti gbọ́ ọ̀rọ̀ Olúwa.
Iṣe Apo 13:44YCE(Yoruba Bible)
Nígbà tí ó di Ọjọ́ Ìsinmi keji, ó fẹ́rẹ̀ jẹ́ pé gbogbo ìlú ni ó péjọ láti gbọ́ ọ̀rọ̀ Oluwa.