Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 13:40YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitorina ẹ kiyesara, ki eyi ti a ti sọ ninu iwe awọn woli ki o maṣe de ba nyin, pe

Iṣe Apo 13:40BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí náà, ẹ kíyèsára, kí èyí tí a ti sọ nínú ìwé àwọn wòlíì má ṣe dé bá yín pé

Iṣe Apo 13:40YCE(Yoruba Bible)

Nítorí náà, ẹ ṣọ́ra kí ohun tí a kọ sílẹ̀ ninu ìwé àwọn wolii má baà dé ba yín