Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 13:35YBCV(Bibeli Mimọ)
Nitori o si wi ninu Psalmu miran pẹlu pe, Iwọ kì yio jẹ ki Ẹni Mimọ́ rẹ ri idibajẹ.
Iṣe Apo 13:35BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ó sì wí nínú Saamu mìíràn pẹ̀lú pé, “ ‘Ìwọ kí yóò jẹ́ kí Ẹni Mímọ́ rẹ rí ìdíbàjẹ́.’
Iṣe Apo 13:35YCE(Yoruba Bible)
Bẹ́ẹ̀ ni ó tún sọ níbòmíràn pé, ‘O kò ní jẹ́ kí Ẹni ọ̀wọ̀ rẹ mọ ìdíbàjẹ́.’