Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 13:24YBCV(Bibeli Mimọ)
Nigbati Johanu ti kọ́ wãsu baptismu ironupiwada fun gbogbo enia Israeli ṣaju wíwa rẹ̀.
Iṣe Apo 13:24BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣáájú wíwá Jesu ni Johanu ti wàásù bamitiisi ìrònúpìwàdà fún gbogbo ènìyàn Israẹli.
Iṣe Apo 13:24YCE(Yoruba Bible)
Kí Jesu tó yọjú, Johanu ti ń waasu fún gbogbo àwọn eniyan Israẹli pé kí wọ́n ṣe ìrìbọmi bí àmì pé wọ́n ronupiwada.