Skip to content
Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 12:25YBCV(Bibeli Mimọ)

Barnaba on Saulu si pada ti Jerusalemu wá, nigbati nwọn si pari iṣẹ-iranṣẹ wọn, nwọn si mu Johanu wá pẹlu wọn, apele ẹniti ijẹ Marku.

Iṣe Apo 12:25BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Barnaba àti Saulu sì padà wá láti Jerusalẹmu, nígbà ti wọ́n sì parí iṣẹ́ ìránṣẹ́ wọn, wọn sì mú Johanu ẹni tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Marku wá pẹ̀lú wọn.

Iṣe Apo 12:25YCE(Yoruba Bible)

Nígbà tí Banaba ati Saulu parí iṣẹ́ tí a rán wọn, wọ́n pada láti Jerusalẹmu, wọ́n mú Johanu tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Maku lọ́wọ́.