Rékọjá lọ sí Àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 11:2YBCV(Bibeli Mimọ)

Nigbati Peteru si gòke wá si Jerusalemu, awọn ti ikọla mba a sọ

Iṣe Apo 11:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nígbà tí Peteru sì gòkè wá sí Jerusalẹmu, àwọn ti ìkọlà ń bá a wíjọ́

Iṣe Apo 11:2YCE(Yoruba Bible)

Nígbà tí Peteru pada dé Jerusalẹmu, àwọn onigbagbọ tí ó jẹ́ Juu dá àríyànjiyàn sílẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ náà.