Iṣe Apo 11:1-2
Iṣe Apo 11:1-2 Bibeli Mimọ (YBCV)
AWỌN aposteli ati awọn arakunrin ti o wà ni Judea si gbọ́ pe awọn Keferi pẹlu ti gba ọ̀rọ Ọlọrun. Nigbati Peteru si gòke wá si Jerusalemu, awọn ti ikọla mba a sọ