Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 11:1YBCV(Bibeli Mimọ)

AWỌN aposteli ati awọn arakunrin ti o wà ni Judea si gbọ́ pe awọn Keferi pẹlu ti gba ọ̀rọ Ọlọrun.

Iṣe Apo 11:1BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Àwọn aposteli àti àwọn arákùnrin ti ó wà ni Judea sì gbọ́ pé àwọn aláìkọlà pẹ̀lú ti gba ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Iṣe Apo 11:1YCE(Yoruba Bible)

Àwọn aposteli ati àwọn onigbagbọ yòókù tí ó wà ní Judia gbọ́ pé àwọn tí kì í ṣe Juu náà ti gba ọ̀rọ̀ Ọlọrun.