Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 10:5YBCV(Bibeli Mimọ)
Si rán enia nisisiyi lọ si Joppa, ki nwọn si pè Simoni wá, ẹniti apele rẹ̀ jẹ Peteru
Iṣe Apo 10:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Sì rán ènìyàn nísinsin yìí lọ sí Joppa, kí wọn sì pe Simoni wá, ẹni ti àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Peteru.
Iṣe Apo 10:5YCE(Yoruba Bible)
Nisinsinyii wá rán àwọn kan lọ sí Jọpa, kí wọn lọ pe ẹnìkan tí ń jẹ́ Simoni, tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Peteru, kí ó wá.