Iṣe Apo 1:5
Iṣe Apo 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Nítorí Johanu fi omi bamitiisi yín, ṣùgbọ́n ní ọjọ́ díẹ̀ sí i, a o fi Ẹ̀mí Mímọ́ bamitiisi yín.”
Pín
Kà Iṣe Apo 1Iṣe Apo 1:5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori nitotọ ni Johanu fi omi baptisi; ṣugbọn a o fi Ẹmí Mimọ́ baptisi nyin, kì iṣe ọjọ pupọ lati oni lọ.
Pín
Kà Iṣe Apo 1