Ṣe àfiwé gbogbo èyà
Iṣe Apo 1:24YBCV(Bibeli Mimọ)
Nwọn si gbadura, nwọn si wipe, Iwọ, Oluwa, olumọ̀ ọkàn gbogbo enia, fihàn ninu awọn meji yi, ewo ni iwọ yàn
Iṣe Apo 1:24BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọn sì gbàdúrà, wọn sì wí pé, “Olúwa, ìwọ mọ ọkàn gbogbo ènìyàn, fihàn wá nínú àwọn méjì yìí, èwo ni ìwọ yàn
Iṣe Apo 1:24YCE(Yoruba Bible)
Wọ́n gbadura pé, “Ìwọ Oluwa, Olùmọ̀ràn gbogbo eniyan, fi ẹni tí o bá yàn ninu àwọn mejeeji yìí hàn
Pín
Iṣe Apo 1YCE