Àmì Ìdánimọ̀ Ohun-èlò Bíbélì
Ṣe Àwárí

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 1:17YBCV(Bibeli Mimọ)

Nitori a kà a kún wa, o si ni ipin ninu iṣẹ iranṣẹ yi.

Iṣe Apo 1:17BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Nítorí ọ̀kan nínú wa ni òun ń ṣe tẹ́lẹ̀, òun sì ní ìpín nínú iṣẹ́ ìránṣẹ́ yìí.”

Iṣe Apo 1:17YCE(Yoruba Bible)

Nítorí ọ̀kan ninu wa ni, ó sì ní ìpín ninu iṣẹ́ yìí.”