Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

Iṣe Apo 1:10YBCV(Bibeli Mimọ)

Bi nwọn si ti tẹ̀jumọ́ oju ọrun bi o ti nrè oke, kiyesi i, awọn ọkunrin meji alaṣọ àla duro leti ọdọ wọn

Iṣe Apo 1:10BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Bí wọ́n sì ti tẹjúmọ́ ojú ọ̀run bí ó ti ń lọ sókè, lójijì, àwọn ọkùnrin méjì tí ó wọ aṣọ funfun dúró létí ọ̀dọ̀ wọn.

Iṣe Apo 1:10YCE(Yoruba Bible)

Bí wọ́n ti tẹjú mọ́ òkè bí ó ti ń lọ, àwọn ọkunrin meji tí wọ́n wọ aṣọ funfun dúró tì wọ́n.