Ṣe àfiwé gbogbo èyà
III. Joh 1:4YBCV(Bibeli Mimọ)
Emi kò ni ayọ̀ ti o pọjù eyi lọ, ki emi ki o mã gbọ́ pe, awọn ọmọ mi nrìn ninu otitọ.
III. Joh 1:4BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ni ayọ̀ tí ó tayọ, láti máa gbọ́ pé, àwọn ọmọ mi ń rìn nínú òtítọ́.
III. Joh 1:4YCE(Yoruba Bible)
Ayọ̀ mi kì í lópin, nígbà tí mo bá gbọ́ pé àwọn ọmọ mi ń gbé ìgbé-ayé òtítọ́.