II. Tim 2:17-18
II. Tim 2:17-18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọrọ wọn yio si mã jẹ bi egbò kikẹ̀; ninu awọn ẹniti Himeneu ati Filetu wà; Awọn ẹniti o ti ṣìna niti otitọ, ti nwipe ajinde ti kọja na; ti nwọn si mbì igbagbọ́ awọn miran ṣubu.
Pín
Kà II. Tim 2