II. Tim 2:16
II. Tim 2:16 Yoruba Bible (YCE)
Yẹra fún àwọn ọ̀rọ̀ asán ati ọ̀rọ̀ ìsọkúsọ, nítorí àwọn tí wọ́n fẹ́ràn irú ọ̀rọ̀ wọnyi túbọ̀ ń jìnnà sí ẹ̀sìn Ọlọrun ni.
Pín
Kà II. Tim 2II. Tim 2:16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn yà kuro ninu ọ̀rọ asan, nitoriti nwọn ó mã lọ siwaju ninu aiwa-bi-Ọlọrun
Pín
Kà II. Tim 2