II. Tim 2:13
II. Tim 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Bí àwa kò bá gbàgbọ́, òun dúró ni olóòtítọ́: Nítorí òun kò lè sẹ́ ara rẹ̀.
Pín
Kà II. Tim 2II. Tim 2:13 Bibeli Mimọ (YBCV)
Bi awa kò ba gbagbọ́, on duro li olõtọ: nitori on kò le sẹ́ ara rẹ̀.
Pín
Kà II. Tim 2