Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. Tes 2:6YBCV(Bibeli Mimọ)
Ati nisisiyi ẹnyin mọ ohun ti o nṣe idena, ki a le ba fi i hàn li akokò rẹ̀.
II. Tes 2:6BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àti pé nísinsin yìí, ẹ̀yin mọ ohun tí ń dá a dúró, kí a bá a lè fi í hàn ní àkókò rẹ̀ gan an.
II. Tes 2:6YCE(Yoruba Bible)
Ǹjẹ́ nisinsinyii, ẹ mọ ohun tí ó ń ká a lọ́wọ́ kò, tí kò jẹ́ kí ó farahàn títí àkókò rẹ̀ yóo fi tó.