Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

II. Tes 2:5YBCV(Bibeli Mimọ)

Ẹnyin kò ranti pe, nigbati mo wà lọdọ nyin, mo nsọ̀ nkan wọnyi fun nyin?

II. Tes 2:5BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ṣé ẹ̀yin kò rántí pé nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín, mo ń sọ àwọn nǹkan wọ̀nyí fún un yín.

II. Tes 2:5YCE(Yoruba Bible)

Ẹ ranti pé a ti sọ gbogbo èyí fun yín nígbà tí a wà lọ́dọ̀ yín.