II. Tes 1:8 - Compare All Versions

II. Tes 1:8 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ẹniti yio san ẹsan fun awọn ti kò mọ Ọlọrun, ti nwọn kò si gbà ihinrere Jesu Oluwa wa gbọ́

II. Tes 1:8 YCE (Yoruba Bible)

Nígbà náà ni yóo gbẹ̀san lára àwọn tí kò mọ Ọlọrun ati àwọn tí kò gba ọ̀rọ̀ ìyìn rere Oluwa wa Jesu.

II. Tes 1:8 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Òun yóò fi ìyà jẹ àwọn tí kò mọ Ọlọ́run àti àwọn tí ń ṣe àìgbọ́ràn sí ìyìnrere Jesu Olúwa wa.