II. Sam 9:9
II. Sam 9:9 Yoruba Bible (YCE)
Ọba bá pe Siba, iranṣẹ Saulu, ó wí fún un pé, “Gbogbo ohun tí ó jẹ́ ti Saulu, ọ̀gá rẹ tẹ́lẹ̀, ati ti gbogbo ìdílé rẹ̀, ni n óo dá pada fún Mẹfiboṣẹti ọmọ ọmọ rẹ̀.
Pín
Kà II. Sam 9II. Sam 9:9 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọba si pe Siba iranṣẹ Saulu, o si wi fun u pe, Gbogbo nkan ti iṣe ti Saulu, ati gbogbo eyi ti iṣe ti idile rẹ̀ li emi fi fun ọmọ oluwa rẹ.
Pín
Kà II. Sam 9