II. Sam 8:15
II. Sam 8:15 Yoruba Bible (YCE)
Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi ṣe jọba lórí gbogbo Israẹli, ó sì ń ṣe ẹ̀tọ́ ati òdodo sí gbogbo eniyan, nígbà gbogbo.
Pín
Kà II. Sam 8II. Sam 8:15 Bibeli Mimọ (YBCV)
Dafidi si jọba lori gbogbo Israeli; Dafidi si ṣe idajọ ati otitọ fun awọn enia rẹ̀.
Pín
Kà II. Sam 8