Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

II. Sam 7:2YBCV(Bibeli Mimọ)

Ọba si wi fun Natani woli pe, Sa wõ, emi ngbe inu ile ti a fi kedari kọ, ṣugbọn apoti-ẹri Ọlọrun ngbe inu ibi ti a fi aṣọ ke.

II. Sam 7:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ọba sì wí fún Natani wòlíì pé, “Sá wò ó, èmi ń gbé inú ilẹ̀ tí a fi kedari kọ́, ṣùgbọ́n àpótí ẹ̀rí Ọlọ́run ń gbé inú ibi tí a fi aṣọ gé.”

II. Sam 7:2YCE(Yoruba Bible)

ọba wí fún Natani wolii pé, “Èmi ń gbé inú ààfin tí wọ́n fi igi kedari kọ́, ṣugbọn inú àgọ́ ni àpótí ẹ̀rí OLUWA wà!”