Dafidi si npọ̀ si i, Oluwa Ọlọrun awọn ọmọ-ogun si wà pẹlu rẹ̀.
Agbára Dafidi bẹ̀rẹ̀ sí pọ̀ sí i, nítorí pé OLUWA Ọlọrun àwọn ọmọ ogun wà pẹlu rẹ̀.
Dafidi sì ń pọ̀ sí i, OLúWA Ọlọ́run àwọn ọmọ-ogun sì wà pẹ̀lú rẹ̀.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò