Ṣe àfiwé gbogbo èyà
II. Sam 3:2YBCV(Bibeli Mimọ)
Dafidi si bi ọmọkunrin ni Hebroni: Ammoni li akọbi rẹ̀ ti Ahinoamu ara Jesreeli bi fun u.
II. Sam 3:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Dafidi sì bí ọmọkùnrin ní Hebroni: Amnoni ni àkọ́bí rẹ̀ tí Ahinoamu ará Jesreeli bí fún un.
II. Sam 3:2YCE(Yoruba Bible)
Ọmọkunrin mẹfa ni wọ́n bí fún Dafidi nígbà tí ó wà ní Heburoni. Aminoni tí ìyá rẹ̀ ń jẹ́ Ahinoamu, ará Jesireeli, ni àkọ́bí.
Pín
II. Sam 3YCE