II. Sam 21:14
II. Sam 21:14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nwọn si sin egungun Saulu ati ti Jonatani ọmọ rẹ̀ ni ilẹ Benjamini, ni Sela, ninu iboji Kiṣi baba rẹ̀: nwọn si ṣe gbogbo eyi ti ọba pa li aṣẹ: lẹhin eyini Ọlọrun si gbà ẹbẹ nitori ilẹ na.