II. Sam 18:5
II. Sam 18:5 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ọba si paṣẹ fun Joabu ati Abiṣai ati Ittai pe, Ẹ tọju ọdọmọkunrin na Absalomu fun mi. Gbogbo awọn enia na si gbọ́ nigbati ọba paṣẹ fun gbogbo awọn balogun nitori Absalomu.