JOABU ọmọ Seruia si kiyesi i pe, ọkàn ọba si fà si Absalomu.
Joabu, ọmọ Seruaya, ṣe akiyesi pé ọkàn Absalomu ń fa Dafidi pupọ.
Joabu ọmọ Seruiah sì kíyèsi i, pé ọkàn ọba sì fà sí Absalomu.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò