II. Sam 13:1
II. Sam 13:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
O si ṣe, lẹhin eyi, Absalomu ọmọ Dafidi ni aburo obinrin kan ti o ṣe arẹwà, orukọ rẹ̀ a si ma jẹ́ Tamari; Amnoni ọmọ Dafidi si fẹràn rẹ̀.