Fò sí àkóónú

Ṣe àfiwé gbogbo èyà

II. Sam 12:2YBCV(Bibeli Mimọ)

Ọkunrin ọlọrọ̀ na si ni agutan ati malu li ọ̀pọlọpọ

II. Sam 12:2BMYO(Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Ọkùnrin ọlọ́rọ̀ náà sì ní àgùntàn àti màlúù lọ́pọ̀lọ́pọ̀.

II. Sam 12:2YCE(Yoruba Bible)

Ọkunrin ọlọ́rọ̀ yìí ní ọpọlọpọ agbo mààlúù, ati agbo aguntan.