II. Pet 3:18
II. Pet 3:18 Yoruba Bible (YCE)
Ṣugbọn ẹ máa dàgbà ninu oore-ọ̀fẹ́ ati ìmọ̀ Oluwa ati olùgbàlà wa, Jesu Kristi. Tirẹ̀ ni ògo nisinsinyii ati títí laelae. Amin.
Pín
Kà II. Pet 3II. Pet 3:18 Bibeli Mimọ (YBCV)
Ṣugbọn ẹ mã dàgba ninu õre-ọfẹ ati ninu ìmọ Oluwa ati Olugbala wa Jesu Kristi; ẹniti ogo wà fun nisisiyi ati titi lai. Amin.
Pín
Kà II. Pet 3