II. Pet 1:13-14
II. Pet 1:13-14 Bibeli Mimọ (YBCV)
Emi si rò pe o yẹ, niwọn igbati emi ba mbẹ ninu agọ́ yi, lati mã fi iranti rú nyin soke; Bi emi ti mọ̀ pe, bibọ́ agọ́ mi yi silẹ kù si dẹdẹ, ani bi Oluwa wa Jesu Kristi ti fihàn mi.
Pín
Kà II. Pet 1