A si le Juda niwaju Israeli; nwọn si sá olukuluku sinu agọ rẹ̀.
Israẹli ṣẹgun Juda, gbogbo àwọn ọmọ ogun Juda sì pada sí ilé wọn.
A kó ipa ọ̀nà Juda nípasẹ̀ Israẹli, gbogbo àwọn ọkùnrin sì sálọ sí ilé e rẹ̀.
Ilé
Bíbélì
Àwon ètò
Àwon Fídíò