II. Kor 4:16
II. Kor 4:16 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori eyi ni ãrẹ̀ kò ṣe mu wa; ṣugbọn bi ọkunrin ti ode wa ba nparun, sibẹ ọkunrin ti inu wa ndi titun li ojojumọ́.
Pín
Kà II. Kor 4II. Kor 4:16 Yoruba Bible (YCE)
Nítorí náà ni a kò fi sọ ìrètí nù. Nítorí pé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ara wa ti òde ń bàjẹ́, ṣugbọn ara wa ti inú ń di titun sí i lojoojumọ.
Pín
Kà II. Kor 4