II. Kor 11:6 - Compare All Versions

II. Kor 11:6 YBCV (Bibeli Mimọ)

Ṣugbọn bi mo tilẹ jẹ òpe li ọ̀rọ, ki iṣe ni ìmọ; ṣugbọn awa ti fihan dajudaju fun nyin lãrin gbogbo enia.

II. Kor 11:6 YCE (Yoruba Bible)

Ọ̀rọ̀ lè má dùn lẹ́nu mi, ṣugbọn mo ní ìmọ̀, ní ọ̀nà gbogbo a ti mú kí èyí hàn si yín ninu ohun gbogbo.

II. Kor 11:6 BMYO (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)

Bí mo tilẹ̀ jẹ́ òpè nínú ọ̀rọ̀ sísọ, kì í ṣe nínú ìmọ̀; ní ọ̀nàkọnà ni àwa ti fi èyí hàn dájúdájú fún yín nínú ohun gbogbo.