II. Kro 14:3
II. Kro 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní (YCB)
Ó gbé àwọn pẹpẹ àjèjì kúrò àti àwọn ibi gíga. Ó fọ́ àwọn òkúta tí a yà sọ́tọ̀, ó sì gé àwọn ère Aṣerah bolẹ̀.
II. Kro 14:3 Bibeli Mimọ (YBCV)
Nitori ti o mu pẹpẹ awọn ajeji oriṣa kuro, ati ibi giga wọnni, o si wó awọn ere palẹ, o si bẹ ere-oriṣa wọn lulẹ