I. Tim 5:1
I. Tim 5:1 Yoruba Bible (YCE)
Má máa fi ohùn líle bá àwọn àgbàlagbà wí, ṣugbọn máa gbà wọ́n níyànjú bíi baba rẹ. Máa ṣe sí àwọn ọdọmọkunrin bí ẹ̀gbọ́n ati àbúrò rẹ.
Pín
Kà I. Tim 5I. Tim 5:1 Bibeli Mimọ (YBCV)
MÁṢE ba alàgba wi, ṣugbọn ki o mã gba a niyanju bi baba; awọn ọdọmọkunrin bi arakunrin
Pín
Kà I. Tim 5